Yetunde Obanla Eleto Aiye Mi lyrics
Nigerian Gospel Lyrics

Yetunde Obanla – Eleto Aiye Mi Lyrics

Views
Print Friendly, PDF & Email

Yetunde Obanla Eleto Aye Mi Lyrics

[Chorus]
Gbo’pe aiye mi
Ọba eleto
Ki ìyá mi to bimi, lontin ṣe to aiye mi 2x

Ètò rẹ ni bimoto waiye
Ìwọ looto ibi mogba
At’ya ati baba mi
Ibi wọn bimi si, ko sẹ́yìn rẹ
Ọjọ́ tabi mi, eto rẹ ni
Oun moje laiye, olori eto re ni
Omo’hun to fẹ́ fimiro, koto dami saiye mi
Olori eto aiye mi
Gbogbo ọpẹ l’ori mi, ìwọ loni
Meto meto aiye mi, mo kan saara sio

[Chorus]

Tori omo’hun ma waiye wada
Oyan áńgẹ́lì irinajo mi tì mí
Ngba mo fori dagi, Olorun ìwọ ni mori
Ninu aipe mi, ofimi sile rara
Loojo erin, ìwọ nikan ni mori
Ọjọ́ ifẹ inu mi ha mimo, iwọ lotumi sile
Ọjọ́ eékún otumi ninu
Ìwọ láàyò mi
Ogo aiye mi, owo rẹ lowa
Olugbe orimi soke
Gba gbogbo ogo
Olumeto mi ẹsẹ o baba

[Chorus]

[Bridge]
Call :Won oje mi maiye
Resp:Ese o baba
Cal:Irinajo mi odoju ru rara rara
Res:Ese ooo baba
Cal:Olumeto to meto aiye mi lati’beere
Res:Ese o baba
Cal:Ose t’oje ki’ya aiye kojemi gbe
Res:Ese o baba
Cal:Igi leyin ogba kan ṣoṣo ti mo gbojule
Res:Ese o baba
Cal:Baba toto baba ṣe fun bàbà to bimi
Res:Ese o baba

Ki iya mi to bimi, lotin ṣe to aiye mi(Till fade)


 

NGL
the authorNGL
Browse our website for latest Nigerian and Foreign Gospel Lyrics, we also provide lyrics for Christian Hiphop songs.

Leave a Reply

0 Shares
Tweet
Share
Pin